GBAJUMO

IRU KILELEYII OLODUMARE, ELEDE BI OMO EEYAN

Ko-jo-eeyan-ko-jo-eranko
ti elede bi ree
Iyalenu nla nisele ohun jo loju awon to ri i bi elede se foyun inu e bi apa kan eniyan, apa kan eranko.
Ohun ta a gbo ni pe lojuese ti elede yii bi arameriiri yii tan lo ti je pe Olodumare. Ni tododo, nnkan n be laye yii o, ati pe, mewaa gan-an lo n sele ni duniyan.
Elede to bi i 










Abami gbaa ree

Post a Comment

0 Comments