GBAJUMO

Showing posts with the label Iroyin yajo-yajoShow all
GOMINA IPINLE EKO TELE, AKINWUNMI AMBODE WO GAU  *EFCC NI WON FI N LE E KIRI
IKU ORO O! WON TUN TI PA OMO NIGERIA KAN NI SOUTH AFRICA *WON RO PE GBOMOGBOMO NI
AARE ONAKAKANFO RANSE SI BUHARI L'ABUJA *O NI, E SO FUN UN DAADAA, EBI N PA ARAALU O
OLÓWÒ, OBA FOLAGBADE OLATERU OLAGBEGI TI WAJA
NOOSI ALABERE TI JEWO, O NI AIMOYE OMO LOUN SOKUNFA PASI PAARO WON LOSIBITU UTH…
O MA SE O! LEYIN WAKATI DIE TO DI DOKITA, WON SI GUN OMOKUNRIN YII LOBE PA L’EKOO
OKU REPETE NILE HAUSA, IJA BURUKU NI WON LO BE SILE NIBE
SEIDU ADEYEMI TO PA OMO IGBAKEJI GOMINA L’ONDO, WON TI NI KI WON LO YEGI FUN UN
O MA SE O: ILE TIJOBA N WO LOWO YA LOJIJI *YANNA-YANNA LAWON EEYAN FARAPA
JIMI AGBAJE TI KI SANWO-OLU KU ORIIRE *SUGBON NISE LAWON OMO EGBE PDP KAN N BINU O
RASAKI ATUNWA TO FIDI REMI NI KWARA TI KI RASAKI APC TO WOLE KU ORIIRE
SULAIMON ADIO ATAWEWE N SOJOOBI LONI-IN *LAWON OLOLUFE E BA N ROJO ADURA FUN UN
EYI NI BI AARE MUHAMMED BUHARI SE JAWE OLUBORI *TI ALHAJI ATIKU ABUBAKAR ATI EGBE E,PDP SI FIDI REMI