GBAJUMO

SAIDI OSUPA FE SERE NLA FAWON OLOLUFE EGBOOGI MEGATO N’ILORIN *OFIFO IKE MEGATO ATI PAKURUMO NI WON YOO FI WOLE

Saheed Osupa

Ilu Ilorin maa mi titi laipe yii, iyen lojo kokanlelogun osu kewaa odun yii nigba ti gbajumo olori fuji nni, Alhaji Saheed Osupa yoo forin aladun da awon ololufee egboogi tuntun nni, MEGATO Energy drink laraya.
Ayeye nla yii ti won pe akori e ni MEGATO DAY yoo waye ni gbongan nla, Art and Culture ni Geri Alimi niluu Ilorin, ipinle Kwara pelu ebun lorisirisi fawon eeyan Kwara.
Yato si oba orin, King Saheed Osupa, awon osere tiata lolokan-o-jokan naa maa peju sibe, bee lawon olorin lorisirisi bii awon oni hip-hop atawon mi-in naa yoo wa forin aladun da awon eeyan laraya.
Ninu atejade ti ileese to n se MEGATO ENERGY DRINK to se agbateru faaji nla yii fi sita lo ti fidi e mule wi pe, “Ofe la gbe eto yii kale fawon ololufee egboogi wa, MEGATO to n ta warawara lowo. Ofe ni o, ko si owo iwole rara, ofifo ike MEGATO meji ati ofifo ike Pakurumo meji lawon eeyan yoo fi wole. Bakan naa ni ebun tun wa lorisirisi tawon eeyan yoo je nibe lojo yen.”
Lati ti ri i ra, won ti ni kaakiri ile-itaja ati ibi tawon alafe ti n se faaji lawon ileetura lo wa, paapaa nileese Top Biz International, Oko Erin Road, niluu Ilorin, ipinle Kwara nibi ti won yoo ti ri MEGATO Energy drink ati Pakurumo ra lopo yanturu.
MEGATO Energy drink ree
MEGATO Energy drinks ti di gbajugbaja bayii, oogun to dara fun okunrin ati obinrin ni, ko ni oti ninu rara, bee lo maa n fun ni lagbara, to tun wulo fun awon okunrin paapaa eni ti ko ba le se deede pelu iyawo e, okunrin ti kinni e kere ju ojo ori e lo, to fe ko gun daadaa, bee lo tun maa n toju awon aisan bii jedi-jedi, opa eyin, to si tun le sise daadaa fun obinrin ti nnka osu e ba n se segesege.
Won ti ni awon anfaani olokan-o-jokan ti ileese ohun se iwadii e finnifinni ree ti won si fi gbe egboogi nla naa jade ti won pe akole e ni MEGATO Sexual Elixir.

Post a Comment

0 Comments