WON N WA GANIYA
TO SONU L’EKOO OMO ODUN MERINLELOGUN (24) NI, ADUGBO GBAGADA PHASE ONE L'EKOO NI WON TI RI I GBEYIN LOJO AIKU SANNDE, OJO KEJIDINLOGBON OSU YII. ENIKENI TO BA RI I LE PE NOMBA YII TABI FI TO AWON OLOPAA TO BA WA NITOSI LETI..... OMO WA KO NI I SONU O!
0 Comments