Aminat Babalola Omotayebi, eni tawon eeyan tun mo si Iya Kekere Eko tun ti de o!
Asiri wo lo wa laarin Omotayebi olorin Islam ati Babajide Sanwo-Olu, oludjie fun ipo gomina nipinle Eko?
Ta leni to da won po, ki lo ni ki awon ara Eko se gan-an fun okunrin oloselu yii?
O ya, e wo fidio yii, ki e le mo ohun to seeele!