E WO SATIFIKEETI MEJEEJI YII, WON NI EYI TO WA LOKE YII NI WON MAA N FUN AWON TO BA KEKOO JADE IWE MEWAA LAWON ODUN 1960S...
ELEYII TI E N WO YII GAN AN NI WON FUN AARE MUHAMMED BUHARI LAIPE YII, BEE WON NI ASIKO YEN NAA NI AARE BUHARI KAWE MEWAA JADE...NIBO NI ORIJINA TI BABA WA?
0 Comments