GBAJUMO

ONA TUNTUN TI A LE GBA SO AGAN DOLOMO REE, BEE LAISAN IJU PAAPAA YOO DAWATI- DOKITA SOLAQ

Okan lara awon egboogi asaraloore, to maa n mojuto orisirisi aisan to le maa sapamo je eda niya lago ara ni Solaq Cleanser n se.
Ni bayii, awon alase ileese naa ti so pe, egboogi ohun tun ti pada sori igba bayii lakotun. Bakan naa ni so pe, ise ti o n se lago ara bayii tun ti po daadaa, paapaa lori awon to n woju Olorun atawon ti aisan ibalopo n da a laamu, ti owo ti tan ni kete, sugbon ti arun ko tan nikun.
Alhaji Dr. Rasheed Fasasi, eni tawon eeyan tun mo si Dr. Solaq ti ba wa soro lori egboogi kosemaani yii. Ekunrere alaye e ree:    
IPO TI SOLAQ CLEANSER WA BAYII
Oruko mi ni Alhaji Rasheed Fasasi, eni ti gbogbo eeya mo si Dokita Solaq, Ona ara ni egboogi wa Solaq Cleanser tun gbe jade bayii.
Lati le mu ise e yato daadaa fun awon ololufee egboogi naa, iyen gan lo mu wa te siwaju nipa ise iwadii wa, eyi to si fun wa lanfaani lati gbe egboogi ohun jade pada lakotun.
Ni bayii, o ti wa kaaakiri ile itaja, bee lanfaani wa fun gbogbo eeyan to ba setan lati je alagbata egboogi alalubarika yii, to maa n sise daadaa lago ara.
BI AWON EEYAN SE LE DI ALAGBATA WA
Ko sese digba ti eeyan ba ko gbogbo owo to ba ni nipamo wa ki o too le darapo mo wa nileeese wa, iyekiye ti e ba ni, e sa maa ko o bo wa, a setan lati fun yin loja, a fe fi tiwa gbe yin laruge ni,  ki eyin naa si fi todo tiyin gbe awa naa laruge pelu ooto inu. Se Yoruba bo won ni bi eeyan ko ba tete reni ba la, nise ni ola maa n pe.
Ti e ba ti n ta a, o ti niye ti o maa je tiyin, ki i se egboogi ti eeyan maa n kowo le lori, to maa gbe owo eni jokoo, ko lo nile ko dowo ni, ohun kan to tun mu egboogi yii yato niyen. Funra e lo maa n polowo ara e, nitori eeyan ko ni i lo o ki o maa ri iyato e lara.
IYATO SOLAQ CLEANSER ATAWON YOOKU
Ohun to mu un yato si awon egboogi cleanser yooku ni pe, ni kete ti e ba ti lo o le o ti maa ri koko ohun ti e torie lo o, ti yoo si di koseemani ninu ile yin.
Ohun kan to tun mu un yato ni pe, bi ohun mimu elerindodo lo se maa n ri lenu, iyen Juice.
Loooto ni orisirisi bitters ati cleanser, iyen awon egboogi to maa n fo idoti ara wa nita, sugbon ti Solaq Cleanser yii yato, nitori leseksese ti o ba ti lo o ni wa bere si rise e, ki i yani nigbe gbuurugbu, bee ni ki i run eeyan ninu, tabi mu eeyan maa bi tabi da wahala sile ninu ago ara eeyan, eleyii maa n tun ago ara se ni, ti alaafia yoo si de ba eeyan lesekese.
AWON ISE MI-IN TO TUN N SE
Gbogbo idoti inu eje, idoti inu ara pata lo maa fo, gbogbo e pata ni Solaq Cleanser maa fo danu. Awon eeyan  gan-an ko je ki a gbadun, paapaa awon ti won ti lo o ri, ti won si mo ise pataki to n se lago ara.
Solaq Cleanser ki i se oloti, omi la fi se e, bee lo n sise daadaa fun eni ti aisan iju, iyen Fibroid n da laamu, ati gbogbo eni to n woju Olorun lori omo bibi. A maa fo idoti to le maa fa idiwo lati ri omo bi, bee lo tun maa n sise daadaa fun awon eeyan ti nnkan osu won ba n se segesege, ti ki i waye deede.
Ti e ba ti lo Solaq Cleanser, gbogbo nnkan to le maa fa idiwo, tabi idoti inu ile omo pata lo maa fo danu, ti eni to n sogbere omo yoo si rerin-in ayo nigbeyin.
Yato si eyi, aisan kan wa ti awon oloyinbo n pe ni Staphylococcus (STD), eeyan le ko latara ibalopo laarin ololufe meji, bee ni eeyan n ko o nile igbonse atawon orisirisi ona mi-in, ti eeyan ba ti lo egboogi Solaq yii, logan ni iyato a de, to maa fo gbogbo idoti to ba ba pade ninu ara danu, ti i aisan yen ko tun ni se eeyan wo mo.
Odun kejo ree ti Solaq Cleanser ti n jade lati ileese wa, ti awon eeyan si n royin e daadaa.
Ko koro rara, bi ohun mimu elerin-dodo lo se ri, oyin ati osan wewe pelu awon eroja asaraloore mi-in la kojo ti a fi se e.
Fun gbogbo eeyan to ba fe je alagbata, anfaani ti si sile bayii, e kan si wa ni ofiisi wa to wa ni N0 51 Ogunnusi road, County Bus stop, Ogba, l’Ekoo.
Bee ni e le pe sori nomba yii: 09099999750.


Post a Comment

0 Comments