GBAJUMO

EYI NI BI AARE MUHAMMED BUHARI SE JAWE OLUBORI *TI ALHAJI ATIKU ABUBAKAR ATI EGBE E,PDP SI FIDI REMI


Ajo INEC ti kede abajade esi ibo Aare to waye lojo ketalelogun osu keji odun yii, Aare Muhammed Buhari gan-an ni won so pe o jawe olubori, nigba ti Alhaji Atiku Abubakar si tele e pelu ibo to le ni milionu mokanla.
Satide, ojo Abameta, iyen lose to koja ni eto idibo Aare waye kaakiri awon ipinle merindinlogoji ati ilu Abuja.  
Lati ojo Monde gan-an ni ajo INEC ti ka ibo ohun, nigba ti yoo si fi di afemoju oni, Wesde, esi ibo ohun ti jade tan patapata.
Ibo milionu meedogun ati egberun lona aadowa-o-le (15,191,848) ni Buhari fi jawe olubori, nigba ti Atiku Abubakar omo egbe oselu PDP tele e pelu ibo milionu mokanla-o-le-egberun-lona ota-le-lugba (11,262,978).
Ni bayii, Aare Mohammed Buhari ni yoo maa ba isakoso orile-ede yii pelu igbakeji e, Ojogbon Yemi Osibanjo titi ti odun 2023.
E WO TABILI YII BI ESI IDIBO AARE SE LO KAAKIRI NIGERIA  
S/N
STATES
APC
PDP
1
EKITI
219,231
154,032
2
OSUN
347,634
337,377
3
FCT
152,224
259,997
4
NASARAWA
289,903
283,847
5
KWARA
308,984
138,184
6
KOGI
285,894
218,207
7
GOMBE
402,961
138,484
8
ONDO
241,769
275,901
9
ABIA
85,058
219,698
10
YOBE
497,914
50,763
11
ENUGU
54,423
355,553
12
EBONYI
90,726
258,573
13
NIGER
612,371
218,052
14
JIGAWA
794,738
289,895
15
KADUNA
993,445
649,612
16
ANAMBRA
33,298
524,738
17
OYO
365,229
366,690
18
ADAMAWA
378,078
410,266
19
BAUCHI
798,428
209,313
20
LAGOS
580,825
448,015
21
OGUN
281,762
194,655
22
EDO
267,842
275,691
23
BENUE
347,668
356,817
24
IMO
140,463
334,923
25
PLATEAU
468,555
548,665
26
KANO
1,464,768
391,593
27
KASTINA
1,232,133
308,056
28
TARABA
324,906
374,743
29
CROSS RIVER
117,302
295,737
30
AKWA IBOM
175,429
395,832
31
BORNO
836,496
71,788
32
DELTA
221,292
594,068
33
BAYELSA
118,821
197,933
34
SOKOTO
490,333
361,604
35
KEBBI
581,552
154,282
36
ZAMFARA
438,682
125,423
37
RIVERS
150,710
473,971
TOTAL
15,191,847
11,262,978


Post a Comment

0 Comments