Bo o lo o yago loro da
lasiko ti ibo aare, ile gbimo asofin agba ati awon asoju-sofin ti won di
kaakiri orile-ede yii loni-in da nipinle Rivers.
Lojiji ni won so pe
wahala buruku yii be sile lagbegbe kan nipinle Rivers, ninu eyi ti agunbaniro
kan ti pade iku ojiji.
Ekunrere alaye nipa
eni to ku yii la o fi to yin leti to ba ya…
0 Comments