GBAJUMO

IDAJO IBO GOMINA L'OSUN: YEYE LAWON EGBE OSELU PDP N FAWON AREGBESOLA SE

WON NI YEYE LAWON EGBE OSELU PDP N FI AWON AREGBESOLA ATI TINUBU SE LOSUN; BI WON TI SE SARE PE EJO KO TE MI LORUN... O JO PE ADEMOLA ADELEKE YOO TUN SE FIDIO KAN LAIPE YII...IJO NLA LOKUNRIN OLOSELU OMO WON NILUU EDE YII YOO JO NINU E PELU....oro n boro bo....eegun alare

Post a Comment

0 Comments