GBAJUMO

LOJO AJINDE JESU, ESTHER IGBEKELE RANSE SI GBOGBO AGBAYE, O NI E JE KA FI IFE ATI ALAAFIA BA ARA WA GBE

Bi gbogbo omoleyin Kristi se n yo ayo ajinde Jesu Kristi Olugbala, gbajumo olorin emi nni, Esther Igbekele ti ro gbogbo Kristeni ati gbogbo eeyan lagbaye lati maa gbe pelu alaafia irepo gidi.
O fi kun un pe bi Jesu Olugbala se jinde yii, gbogbo ohun ara otun lo maa jinde laye kaluku, sugbon ki a gba ife ati alaafia laaye ni gbogbo ibikibi.
Okan pataki ninu awon to n korin emi yii, to si loruko daadaa kaakiri agbaye ni Esther n se, bee lo so pe, oun sese gbe orin aladun kan sori ero alatagba YouTube ni...
Eyin naa e wo o lori atona to wa nisale yii:
https://youtu.be/jQ5G2vMt1Zs

Post a Comment

0 Comments