GBAJUMO

MEGATO RICE ATI GARRI MEGATO GBALU KAN *ILEESE OKO OLOYUN TO N SE E TI SO PE WITIWITI LO N TA


Bo se ku dede ki aawe awon Musulumi bere, ileese to n se Megato Rice ati Gaari Megato ti so pe ounje ohun ti wa nigboro daadaa, bee ni owo e ko ga ni lara rara.
Ninu oro ti okan lara awon alase ileese naa ba wa so lo ti salaye pe, “Bi a ti se se odinwon orisirisi ounje asaraloore to n jade nileese wa, iyen MEGATO RICE ati MEGATO GARRI, a se e lona ti o fi le wulo fawon eeyan. Iru asiko ta a wa yii, anfaani wa daadaa fun awon ti won fe gba aawe lati wa ra a lopo yanturu, nitori o see fun eeyan lasiko yii gege bi ebun ounje aawe.
“Fun gbogbo awon to fe seto waasi ita gbangba ninu aawe, o se e pin fawon eeyan gege bii ebun, bo ti se wa ni paali-paali, bee lo tun wa lejewon ninu paali kookan. Eyi to mu un rorun lati fun awon eeyan gege bi ounje aawe tabi nnkan odun”
Osise ileese to n gbe awon ounje asaraloore yii jade ti so pe, ojulowo ni Iresi Megato, bee naa ni gaari to n jade lati ileese naa dara fun gbogbo ohun ti eeyan ba fe fi se yala ka te e ni eba tabi mimu.


O ni, orile-ede yii naa lati n se e, bee ni won kun fun eroja asaraloore; ki i se iresi oniroba tabi onike, abi eyi ti won ti po kemika mo. Gaari wa naa dara, awa la n se e, o dara lenu, bee lo wuyi loju. Ose ti o n jade nileese wa naa dara, ki i je owo, kii baa so je, bee lo ni oorun to fani-mora.”

Orisirisi nnkan ni Ileese MEGATO n se, lara e ni, MEGATO Elizir, eyi to maa n fun okunrin lagbara, to tun maa n ran obinrin lowo daadaa lati mojuto gbogbo awon aisan to le maa daamu won lago ara, bee gege ni egboogi Gbe Body e, ti oun naa n milu titi bayii.
Yato si awon oogun asaraloore yii, ileese naa lo n se Gaari, Iresi ati ose MEGATO pelu awon nnkan mi-in ti eeyan maa n lo ninu ile.  
Ni bayii, won ti ke si awon to maa n senawo, ti won ko le ma pin ebun lode ariya lati maa ra awon ohun elo ati ounje to n ti ileese  naa jade.
Won ti ni ojulowo ni, bee lo tun dinwo, ti ko ga’ni lara rara. Ileese OKO OLOYUN lo n se e, bee le le ri awon nnkan wonyi ra nileese won to wa ni No 1, OKO OLOYUN Avenue, Hotel Bus stop, along LASU road, Igando, Lagos. 08034342411, 08030468955   


Post a Comment

0 Comments