Ojo lojo ti Iyalode Ojodu, Oloye Yetunde Babajide ko awon omo egbe e wole Ife...nise lo ko won dewaju Ooni gbangba... Oba Enitan Adeyeye Ogunwusi, Ojaja Keji...oun atawon omo egbe ni won lo da Kabiesi lola; ojo yen gan an ni won so Arole OOdua di baba isale ajo AFCO, iyen Grand Royal Father International for AFCO in Nigeria.
Bii osumare ni Iyalode atawon omo egbe e n tan o...bee lojo ohun ye won gidigidi..
Kabiesi lanu koto; orin nla ni baba n ko...bee lo n so pe....YETUNDE ooo..YETUNDE MI DA....YETUNDE l!...
Iyalode Ojodu ti dupe o...bee lo fi awon eeyan e lokan bale wi pe lasiko ijoba Buhari yii; didun losan yoo so nigbeyin oro.
0 Comments