GBAJUMO

IKU ORO O! WON YINBON PA BUNMI OJO OMO EGBE OSELU APC L’EKITI


Okan pataki ninu asaaju egbe oselu APC lawon hayakila kan yinbon pa loni-in, ojo Eti Fraide.
Bunmi Ojo ni won pe oruko okunrin oloselu yii, eni to ti figba kan je amugbalegbee fun gomina ipinle naa tele, Ogbeni Segun Oni. Ohun ti enikan tisele ohun soju e so ni pe gbagede kan tawon eeyan ti maa n woran boolu ni won ka a mo niluu Ado, ti i se olu ipinle Ekiti, nibe gan-an ni won pa a si.
Ekunrere bi isele yii se waye, e o maa ka a laipe.

Post a Comment

0 Comments