![]() |
Seneto Obadara |
![]() |
Ibikunle Amosun |
Bo
si ti sọ ọ
tan lawọn ọmọlẹyin
ẹ ti wọn
wa nibẹ ti n fo soke, bi ẹni
ti ko gbọ iru ẹ
ri pe Amosun tun fẹ
lo sile igbimo asofin
agba leekan si i, ti wọn
si n
ki ara wọn ku oriire. Ṣugbọn
ko too
digba naa ni Sẹnẹto
Ọbadara ti fi erongba ẹ
han lati jade dupo naa lẹẹkeji
labẹ asia ẹgbẹ
oṣelu APC.
Afi
bo ṣe di aarọ
ọjọ
Ẹti, Fraide ti Sẹnetọ
Ọbadara gbe atẹjade
kan sita pe niwọngba ti Gomina Amosun
ti sọ ipinnu ẹ
pe oun fẹ dije dupo, oun fipo
naa silẹ fun un. Awọn
eeyan ko kọkọ
gbagbọ tẹlẹ
pe Ọbadara to ti n leri pe
oun yoo tun se e leekan si i lọdun
2019, ni ko tiẹ janpata to fi fipo
naa silẹ bayii.
Awọn
ọmọ
ẹgbẹ
oṣelu naa ti wọn
gbọ bi ọkunrin
naa ṣe sọ
pe oun ko dupo mọ, ti so pe ẹru
Amosun lo n ba a, ati pe ko fẹ
fowo ẹ jona ni. Wọn
ni bi ko ba juwọ silẹ,
ti Amosun ko dije, o see se ki won ma fun un lanfaani lati dije si i, nitori ko si
ninu awon to n tele gomina ohun tẹlẹ.
Bo
tilẹ jẹ
pe ọkunrin naa sa ipa fawọn
iṣẹ akanṣe
to ṣe lawọn
aarin gbun-gbun
ipinlẹ Ogun, eyi ti wọn
ni ẹni to wa nibẹ
tele
ko ṣe
ida ogun ẹ. Won ni, kani Ọbadara
ni igboya ni, ko yẹ ko tete gbe igbesẹ
to gbe yẹn. Idi niyi ti wọn
fi ni ẹru Amosun lo n ba a, ati pe ko fe na owo to
ti ri ko jo danu, nitori o see se ki kinni ohun ma bo si i
lowo.
Awọn
kan tun sọ pe ohun
to mu ki Ọbadara tete gbe igbeṣẹ
naa ni pe
ko fe ba Gomina Amosun ma fa ipo ohun, eyi to see se ko sakoba fawon
nnkan to ni nipinle ohun bii ileese, paapaa redio
to da silẹ to pe ni Sweeth FM.
0 Comments