Iroyin to n de setiigbo wa ni pe, gomina tele nipinle Ekiti,
Ogbeni Peter Ayodele Fayose nijamba moto lori biriji afara eleeketa, iyen 3rd
Mainland bridge loni-in.
Ninu
oro oluranlowo gomina tele yii, lori eto iroyin, Ogbeni Lere Olayinka ti so pe
loooto nisele ohun waye, sugbon Olorun ko je ki ijanba moto naa le ju bi awon
se lero lo. Bakan naa lo so pe, awon dokita ti n toju gomina tele ohun, ti alaafia
si ti n to o lara.
0 Comments