GBAJUMO

AJO INEC KEDE WI PE KO SI IBO MO LONI-IN* WON LO DI SATIDE TO N BO



Ajo eleto idibo ile wa, INEC ti sun ibo aare atawon ile igbimo asofin agba to ye ko waye loni-in si ojo Satide, Abameta to n bo.
Saaaju asiko yii, lati irole ojo Eti, Fraide ni won so pe ipade ohun ti bere laarin alaga ajo INEC, Ojogbon Mahmood Yakubu pelu awon alaga mejila mi-in ti won je alenuloro atawon awon ara ile okeere ti won wa bojuto bi eto idibo ohun yoo se lo. Ohun ti won n sasaro le lori ni boya ki won sun un siwaju tabi maa ba eto ohun lo.
Ohun ti won so pe won n se asaro le lori ni awon kudie-kudie kan to sele lori ipese ohun elo ti won yoo fi dibo lawon ipinle kan loni-in, ki ibo ohun le kesejari.
Ekunrere alaye yii le o maa ba pade laipe yii


Post a Comment

0 Comments