Asiri ohun
to mu gomina ipinle Oyo, Abiola Ajimobi fidi remi ninu eto idibo to waye lojo
Satide to koja ti han sita bayii, ohun ti awon eeyan si n so ni pe, okunrin naa
fenu ko nibi kan ni o.
Ni bayii,
fidio kan ti wa nigboro bayii, eyi to fidi e mule wi pe, gomina yii lo da
majemu nibi kan, ati pe ohun to sele si yii, adehun to se nibe lo fa a.
Dokita
Kola Balogun to dije labe asia egbe oselu PDP lo jawe olubori lati soju awon
eeyan Ibadan nile igbimo asofi agba pelu ibo to le ni egberun lona
marunlelogorun-un (105,720), nigba ti Gomina Abiola Ajimobi ni ibo egberun
mejilelaadorun o le die (92,218)
Bi gomina
se fidi remi ree o, sugbon ohun tawon eeyan kan so ni pe ohun ti Abiola Jimobi
toro lowo Olorun gan-an lo ri. Won ni okunrin oloselu yii toro ohun meta, bee
lo be Olorun wi pe ti o ba ti fun oun nikan meta ohun, oun ko ni i wa ipo kankan
mo leyin ti oun ba se gomina tan nipinle Oyo.
Enikan to
ba wa soro so pe, “Boya omo Ibadan yii ti gbagbe wi pe oun ti seleri fun Olorun
niwaju awon afaa ni o, eyi gan an lo ya awon eeyan lenu nigba to tun so pe oun
fe pada si ile igbimo asofin agba. O gba tikeeti loooto, bee lo si tun polongo
ibo, to tun dije pelu, sugbon o jo pe Olorun n duro de e, n lokunrin naa ba fidi remi bii apo ewa.”
E WO FIDI
YII
0 Comments