Loni-in ni, ko ni i
d'ola, oni yii gan an ni Ademola Adeleke, Seneto onijo yoo mo boya oun gan an
lo ye nipo gomina nipinle Osun tabi Isiaka Oyetola ti won so pe o la eyin e
mole ninu ibo to waye nipinle Osun lodun to koja.
Awon adajo ni yoo da a
o...bee lawon ara ipinle Osun n reti gidigidi...nibi toro ohun yoo yori si, oju
ree iran ree!
0 Comments