GBAJUMO

O MA SE O: ILE TIJOBA N WO LOWO YA LOJIJI *YANNA-YANNA LAWON EEYAN FARAPA

Ile kan to wo ree 
Bi a ti se n ko iroyin yii, ninu ibanuje lawon eeyan tun wa nigboro Eko bayii, paapaa laduugbo Oke-aarin lori bi ile kan se tun dawo, ninu eyi ti opo ti farapa yannayanna.
Won ni, ile to wo yii wa lara Ile ti ijoba ti sami si wi pe o ti di egeremiti ni. 
won ni lati ana gan an ni won ti n wo o, ati pe lasiko tawon Hausa to n sise nibe lowo n ba ise won lo lawon opo kan ye, bo se di pe ile ohun da le won lori niyen.
Digbadigba la gbo pe won sare gbe won lo si osibitu.
Ekunrere e le o maa ba pade to ba ya

Post a Comment

0 Comments