GBAJUMO

AFEEZ OWO ATI MIDE FUNMI MARTINS...ASIRI TOPO EEYAN KO MO NIPA WON REE

Lodun naa lohun-un, lojiji ni gbajumo osere tiata nni, FUNMI MARTINS jade laye, ibanuje dori agba kodo, bee lomo e, Mide Martins; ba ba ara e ni kolobo.
Bi eru agba se jale Mide lejika niyen, bee ki i se oun nikan ni gbajumo osere tiata to doloogbe yii bi, o lawon aburo daadaa, koda omo kekere jojolo wa ninu won pelu.
Sa o, awon Yoruba bo won ni ko ni i buruburu ko ma ku enikan mo ni, odomokurin kan wa to sunmo Funmi Martins daadaa nigba aye oloogbe naa, Afeez Abiodun lo n je, Owo lawon eeyan tun mo on si. Omo ilu oke ni, ati pe omo odo agba ti o mowo we daadaa lokunrin omo Oke Ogun n'Iseyin yii n se.
Ni tie, ko figba kankan won nile awon Funmi Martins tele, bo se di pe okunrin yii bere si se bii baba ati iya fun awon omo ti Oloogbe da sile ree o.
Ki oloju si too se e, oro ife ti bere laarin Afeez Owo ati Mide, nigba ti Edumare yoo si se oore ohun tan, nni gbogbo eran súnkunsí ti won n se ni koro yara ba doyun, n ni ewe ba so.
Eremode ojosi lo pada to dododo mo won lowon, ti ajosepo won si so won di molebi alayo loni-in.
Gbogbo hun...gbogbo he....Afeez Owo ma ni Mide bimo fun, bee lomobinrin yii n saaye agba lodede e bo tile je pe awon alaimokan ko mo ipile oro ife won...

Post a Comment

0 Comments