GBAJUMO

NOOSI ALABERE TI JEWO, O NI AIMOYE OMO LOUN SOKUNFA PASI PAARO WON LOSIBITU UTH…


Wahala wa o! obinrin noosi kan ti jewo bayii o!O ti so pe, “Aimoye omo ni mo ti se pasi-paaro won nileewosan UTH nigba kan ri…”
O ni gbogbo omo ti won ba bi laarin odun 1983 si odun 1995, o ni ki won ma ro wi pe ile baba ati iya won gan an ni won wa yen o, nitori nise loun se pasi-paaro awon omo nigba yen.
Ohun ti obinrin noosi yii so ni pe, ohun ko ri i bi ise ibi rara, ati pe bi eni sawada lasan loun ka a kun, ti inu oun si maa n dun daadaa ti awon eeyan ba n gbe omo ti ki i se tiwon lo sile.
O ni, idi ti oun fi n jewo ese bayii ni pe, aisan buruku kan ti kolu oun, bee ni olojo le de nigbakuugba, oun ko si fe lo si orun lai ma jewo ise ibi yii…oro ree abi oran? 



Post a Comment

0 Comments