
Oba
Folagbade, Olateru Olagbegi, Olówò ti ilu Òwò nipinle Ondo ti waja leni odun metadinlogorin (77).
Afemoju, Ojoru
Wesde ni Kabiyesi waja. Ojo kerindinlogbon osu kefa odun 1941 ni
won bi i.
Kabiyesi, Olowo ti ilu Òwò yii ni alaga igbimo lobaloba ipinle Ondo ko too jade laye, bee lo gbade lowo
baba re, Olateru lodun 1999
0 Comments