Won lobinrin naa ti loyun, okunrin osere tiata kan to maa n se ipata daadaa ninu sinima ni won so pe o fun Toyin loyun. Kolawole Ajeyemi, eni ti won tun maa n pe ni Awilo lo ba Toyin se ere lile ninu yara titi, tiyen fi loyun mo on lowo.
Okan lara awon osere tiata to gbajumo daadaa niluu Abeokuta ni Awilo n se.
Pelu iroyin yii, a je pe adura Toyin ti gba niyen, nitori orisirisi okunrin losere tiata omo ipinle Edo yii ti fe daadaaa, ti omo ko si ninu igbeyawo tabi ajosepo won.
0 Comments