Bo tile je pe awon eso agbofinro, paapaa awon eso alaabo ojupopo FRSC se duro wamu, sibe awon eeyan yii ko bikita won rara. Bi omode se n gbon on, lawon agba n bu u. Ohun tenikan si so ni pe ere iku gbaa ni won n se.
Ohun ti a gbo ni pe ipinle Eko ni oko ohun ti n bo, ki o too subu sojuna Ibadan si Eko lagbegbe Muslim tawon eeyan si so epo di omi ti won n gbo on laibikita agbako to le sele lojiji.

E wo bi awon eeyan yii se n fiku sere
0 Comments