Ni kete ti eto idibo ti bere nipinle Ekiti loni-in ni
orisirisi fidio ti gba igboro kan. Bi awon kan se n sare loo gbowo lowo awon
oloselu kan, bee gege ni ojo adura n ro lori awon oludije, tawon omo egbe osleu
si n korin fawon mi-in bii eni pe won ti jawe olubori.
Ninu fidio to wa labe iroyin yii gege bi ileeese BBC se gba a sile, nibe gan-an le o ti ri oju awon eeyan ti won lo n gbowo ati egbe oselu ti won ni ki won dibo fun leyin ti won gba owo egberun merin naira (N4000) tan.
Bo tile je pe bii baba-esua lawon oludije po, sibe awon meji
kan pataki lawon eeyan n gboruko won julo. Kayode Fayemi to n dije labe asia
egbe oselu APC ati Ojogbon Kolapo Olusola to je omo egbe oselu PDP.
![]() |
Kayode Fayemi |
Aarin awon meji yii ni itakangbon ohun ti gbona yeye, ohun
to si han daju ni pe, okan ninu won naa ni yoo jawe olubori.
Bi eto idibo ti se fe bere lariwo ti gbagboro kan wi pe nise
lawon egbe oselu kan n pin owo fawon eeyan. Bawon kan se n so pe Fayose atawon
eeyan e ni won n pin owo, bee lawon mi-in so pe awon egbe alatako ni.
Lara awon
oludije mi-in ti won jo n fa a mora won lowo loni-in ni Akinloye Ayegbusi (SDP); Segun
Adewale (ADP); Bisi Omoyeni – Mega Party of Nigeria (MPN); Abiodun Aluko –
Accord Party.
Awon yooku ni; Bode Olowoporoku – Nigeria Democratic Congress Party (NDCP); Shola Omolola Action Alliance (AA); Agboola Olaniyi Alliance for Democracy (AD); David Adesua – African Democratic Congress (ADC); Lucas Orubuloye All Grassroots Alliance (AGA); Stephen Oribamise All Grand Alliance Party (AGAP); Tunde Afe – Abundant Nigeria Renewal Party (ANRP); Saheed Jimoh – African Peoples Alliance (APA); Tope Adebayo – Advanced Peoples Democratic Alliance (APDA); Ayodeji Ayodele – All Progressives Grand Alliance (APGA); Adegboye Ajayi – Better Nigeria Progressive Party (BNPP); Olajumoke Saheed – Democratic Alternative (DA); Olalekan Olanrewaju – Democratic Peoples Congress (DPC); Yinka Akerele – Democratic Peoples Party (DPP); Adewale Akinyele – Green Party of Nigeria (GPN); Sule Ganiyu – Freedom and Justice Movement (FJP); Tosin Ajibare – Independent Democrats (ID);
Temitope Amuda – KOWA Party; Sikiru Lawal
– Labour Party; Olabode Jegede – Mass Movement of Nigeria (MMN); Oladosu
Olaniyan – Northern People’s Congress (NPC); Babatunde Alegbeleye – National
Democratic Liberty Party (NDLP); Dada Ayoyinka – People for Democratic
Change (PDC); Goke Animashaun – Progressive Peoples Alliance (PPA);
Olusegun
Adeleye – United Democratic Party (UDP); Jacob Gboyega – Unity Party
of Nigeria (UPN); Fakorede Ayodeji – Young Democratic Party (YDP) ;Omotayo
Gabriel – Young Progressives Party (YPP)
![]() |
Kolapo Olusola |
Awon yooku ni; Bode Olowoporoku – Nigeria Democratic Congress Party (NDCP); Shola Omolola Action Alliance (AA); Agboola Olaniyi Alliance for Democracy (AD); David Adesua – African Democratic Congress (ADC); Lucas Orubuloye All Grassroots Alliance (AGA); Stephen Oribamise All Grand Alliance Party (AGAP); Tunde Afe – Abundant Nigeria Renewal Party (ANRP); Saheed Jimoh – African Peoples Alliance (APA); Tope Adebayo – Advanced Peoples Democratic Alliance (APDA); Ayodeji Ayodele – All Progressives Grand Alliance (APGA); Adegboye Ajayi – Better Nigeria Progressive Party (BNPP); Olajumoke Saheed – Democratic Alternative (DA); Olalekan Olanrewaju – Democratic Peoples Congress (DPC); Yinka Akerele – Democratic Peoples Party (DPP); Adewale Akinyele – Green Party of Nigeria (GPN); Sule Ganiyu – Freedom and Justice Movement (FJP); Tosin Ajibare – Independent Democrats (ID);
![]() |
Abiodun Aluko |
0 Comments