Bi awon Musulumi lagbaye se n
palemo ayeye odun ileya, ijoba
![]() |
Minisita oro abele, Dambazau |
Loni-in ni Tosde,
Ojobo ni Minisita foro abele, Ogbeni Abdul-Rahman Dambazau kede e.
Minisita yii ti ki
gbogbo omo orile-ede yii ku oriire ayeye odun naa, paapaa awon elesin Musulumi,
bee lo ro won lati lo asiko naa fi wa ife laarin ara won atawon eeyan orile-ede
yii lapapo.
Siwaju si i, o ti ro awon eeyan orile-ede yii lati tubo gbaruku ti ijoba
apapo ki idagbasoke to peye le ba tolori-telemu ni Nigeria.
0 Comments