Kemi Adeosun, minister
fun eto isuna owo lorile-ede yii ti kowe fipo e sile.
Iroyin to gba
igboro kan bayii ni pe, obinrin omo ipinle Ogun yii gbe igbese ohun latari
wahala ti won ko ba a lori iwe eri isinjoba (NYSC) ti won so pe ko ni.
Ni bayii, ohun
ti o foju han bayii ni pe, obinrin yii ti kuro ninu ijoba Buhari, ati pe ohun
tawon eeyan kan n so ni pe, o see se ki ileese Aare mo nipa igbese to gbe yii,
paapaa bi igbaradi idibo odun 2019 se n sunmo.
Ekunrere iroyin yii n bo lona…
1 Comments
Odabe kiwon maba lojuje, aseju awon APC tipoju
ReplyDelete👏👏👏👏👏👏