GBAJUMO

IKUNLE ABIYAMO O! E O RI BI WON SE GBE OMO TUNTUN JU SAKITAN

Omo tuntun ree
lori akitan
Ko seni to ri omode tuntun jojolo yii ti ko maa gbe iya tabi enikeni to seru eyi sepe nla.
Nise lawon eeyan sadeede ba omo tuntun jojolo kan ninu lailoonu lori akitan. Bi awon eeyan se ri ni kaluku n sepe le eni to seru e.
Ju gbogbo e lo, nibi ti olowo ti n sunkun airibi lawon kan ti n gbe tiwon ju sakitan...

Post a Comment

0 Comments