Adugbo kan l’Ekoo ni won ti ri i,
bee lawon molebi e ti so pe, ko si ohun kan bayii to se e, ati pe saka lara omo
ohun da.
Ni bayii, won ti dupe lowo gbogbo
araalu, ti won ba won dide ji giiri soro omo to sonu ohun, sugbon ti Olorun ti
se e ni riri bayii.


0 Comments