Fidio kan to tun gba igboro kan
bayii ni eyi ti Oluaye Fuji. Alaaji Wasiu Ayinde, Anifowose, oko Sikira sese
tun gbe jade, nibi to ti n polongo ibo fun egbe oselu kan, to si tun n pe awon
mi-in lonijekuje.
Awon wo lo n ba a wi gan-an, e
wo fidio yii:
0 Comments