Ola Ojobo, Tosde ojo
ketadinlogbon osu yii ni ayeye ikojade rekoodu tuntun, CHANGING OVER latowo
gbajumo olorin fuji nni, Alhaji Saka Ayinde, eni tawon eeyan tun mo si Saka
Orobo yoo waye.
Ile igbafe kan to n je
Finishing Touches Hotel & Lounge lojuna Lekki, Epe, Expressway, ni Ayo bus
stop, legbee Greenland Estate, Olokonla Ajah, l’Ekoo lo so pe eto ohun yoo ti
waye. Nibi ti won yoo ti ko rekoodu tuntun ohun jade. Aago merin leto ohun yoo bere, nibi ti awon olorin nla nla
naa yoo ti darapo mo on lati ba a seye ohun pelu awon sorosoro ati osere tiata
pelu.
E WO FIDI YII…
0 Comments