GBAJUMO

BUHARI ATI BOLA TINUBU: WON MA NI KO SIJA KAN BAYII LAARIN WON

Saaju asiko yii, iroyin to gba ilu kan ni pe, ija buruku ti be sile laarin Aare Muhammed Buhari, ati asiwaju oloselu ninu egbe APC, Asiwaju Bola Ahmed Tinubu, sugbon logan ni gomina ipinle Eko tele naa yo si won nile ijoba niluu Abuja, bee lawon eeyan n jara won leekanna, ti won n bira won wi pe, nibo gan an ni Jagaban Borgu n lo.
Awon ti won n bira won gan an ko ti i daamu jinna, ti foto ti e n wo yii fi bo sode ita gbangba. Ohun to si foju kan ni pe, Bola Tinubu wa ba Aare lalejo ni, ati pe okunrin naa je saari l'Ekoo, o si wa sinu pelu Aare nile ijoba niluu Abuja.
Aworan yii gan an naa lo pa enu awon alaheso mo, eyi to fidi e
mule wi pe ko si wahala kan bayii laarin awon mejeeji, digbi ni ajosepo won wa, ti imule aarin won si duro daada.
Sa o...eni ti yoo gba ipo lowo Buhari lodun 2023 ni apa iha
Guusu....o jo pe Olorun nikan lo si mo on bayii o…sugbon sa, oju ree iran ree!


Post a Comment

0 Comments