GBAJUMO

GBAJUMO OLORIN MUSULUMI, FAUZIYYAH OLOKIKI N SOJOOBI LONI-IN *NISE LAWON OLOLUFE E N DUNNU


Gbajumo olorin esin Islam nni, Alhaja Fauziyyah Adeyemi, eni tawon eeyan tun mo si Olokiki Omo n sojoobi loni-in bee lo ti fi da awon ololufe e loju wi pe, ohun ara otun n bo lodo oun laipe yii.
Ninu atejade to fi sowo si Magasinni yii lo ti so pe, “Mo dupe lowo Olorun to fun mi ni anfaani lati tun se ayeye ojoobi mi-in laye. A dupe o, paapaa lori ohun gbogbo, ope ni lori alaafia to fun wa, bee nise wa naa n te siwaju, mo si dupe lowo awon ololufe mi, iyen Olokiki Omo Fans Club, nile loko atawon ti won wa loke okun.
“Won ye mi si, mo si toro ki Olorun tubo ba mi maa ye awon naa si ju bayii lo. Laipe yii ni a o gbe ise nla kan jade, lara awon eto ti a ni sile fun odun yii, bee lo maa larinrrin pelu.”
Okan lara awon olorin Musulumi to n se daadaa loni-in ni gbajumo akorin yii n se, bee loun naa ti gbe awon rekoodu akonilogbon jade lorisirisi.  


Post a Comment

0 Comments