GBAJUMO

O MA SE O, GBAJUGBAJA OLORIN MUSULUMI ABU RIDOH KU LOJIJI *ADANU NLA NIKU E JE FUN GBOGBO MUSULUMI- TIDIBODO, AARE PISMAN

Pelu omije loju lawon eeyan fi gbe gbajumo olorin Muslumi nni, Abu Ridoh Asinleke gege, ti won si ti sin in nilana esin Islam.
Ninu oro Aare egbe awon olorin Islam, PISMAN, Alhaji Ibrahim Tidibodo lo ti sapejuwe okunrin olorin yii gege bi eeyan Olorun, ti o fi imo ati ebun ti Olorun fun un fi pe ipe si oju ona esin Islam.
Owuro kutu oni ni won so pe okunrin naa jade laye, bee ni won ti sin in nilana esin Islam siluu Ibadan. Ekunrere bi isele ohun se waye, a o maa fi to yin leti.





Post a Comment

0 Comments