GBAJUMO

GOMINA IPINLE EKO TELE, AKINWUNMI AMBODE WO GAU *EFCC NI WON FI N LE E KIRI


Niluu Epe, iyen nipinle Eko ni awon ajo to n gbogun ti jegudu-jera ati iwa ajebanu ya lo laipe yii nibi ti won ti ye gbogbo ile gomina ipinle Eko tele, Akinwumi Ambode wo finnifinni.
Ileese iroyin kan lori ero ayelukara, ti oruko e n je TheCabe ti so pe agbenuso fun ajo EFCC, Tony Orilade, naa jerii wi pe loooto lawon lo sile okunrin naa lati ye ibe wo daadaa.
Bi ohun gbogbo se lo, la o maa fi to o yin leti...


Post a Comment

0 Comments