GBAJUMO

KEMI AFOLABI OSERE TIATA WO KAABA LO MI MECCA...E KA OHUN TO LO N SO NIWAJU OLUWA


Lati orile-ede Saudi Arabia lohun-un...KEMI AFOLABI gbajumo osere tiata fi ohun ranse...bo ti n dupe bee lo gbadura fun gbogbo Musulumi aye pata atawon ti won fadura ran an lowo nigba ti aisan da a dubule ni Mecca...a lo so pe, gbogbo erongba rere ti kaluku ni Olorun Allah yoo se nirorun...

Post a Comment

0 Comments