EGBE AWON OSISE TI KEDE WI PE KO SI
IYANSELODI MO
Egbe awon osise, NLC ti fagile
iyanselodi to ye ko bere lowuro yii.
Te o ba gbagbe, koko ohun ti ijoba atawon
egbe osise n fa mora won lowo ko ju ekunwo owo osu awon osise ti awon osise n
beere fun.
Egbe osise lawon fe maa gba egberun
lona ogbon naira losoosu (N30,000) gege bi owo osu osise to kere ju, nigba ti ijoba
so pe oun ko le san ju egberun lona mejilelogun naira ati eedegbeta naira (N22,500)
lo.
Ohun to fa wahala ree, eyi to mu
egbe osise kede ki iyanselodi bere lowuro oni, ojo Tusde, Isegun, sugbon leyin
opo wakati ti egbe naa ati ijoba apapo fi sepade, won ti kede wi pe ki awon
eeyan awon si gbagbe iyanselodi ohun na.
Ekunrere
bi won se pada yannju oro ohun la o maa fi to yin leti to ba ya....
4 Comments
E Ku iee taakun-taakun naa, Ko nii reyin o.
ReplyDeletease Edumare
DeleteOun toman mu inu midun ju ni pe,larin awon iwe iroyin toku,iwe iroyin alaroye agbaye nse ise tokan Tara.won kosi gbeyin lati ma gbe iroyin tonlo lasiko jade.iwe iroyin ede abini mi.ere lomo oloja nje labo oja.eo kere oko dele oooo...
ReplyDeletee seun a dupe...a o maa ri yin ba
ReplyDelete